Open
Conversation
Member
|
Thank you very much for the PR. Have these texts been verified as having the correct diacritics (Àmì ohùn)? |
ruohoruotsi
reviewed
Oct 15, 2022
BBC/bbc-sport-yoruba.csv
Outdated
| "Ìdíje bọ̀ọ́lù àwọn obìnrin, WAFCON 2022 gbérasọ ní Morocco"," Oríṣun àwòrán, cafonline Ọjọ keji, oṣu Keje, ọdun 2022, ni idije fun ife ẹyẹ bọọlu awọn obinrin ni Afrika, Women's Africa Cup of Nations, yoo bẹ̀rẹ̀ ni orile-ede Morocco. Ti ọdun yii si ni igba akọkọ ti orile-ede mejila n kopa ninu idije naa. Saaju asiko yii, orile-ede mẹ́jọ lo ma ń kopa. Bakan naa lo jẹ pe igba àkọ́kọ́ re e ti Morocco gbalejo idije naa. Papa ìṣeré mẹta ni yoo ti waye, n'ilu Rabat olu ilu Morocco, ati ilu Casablanca laarin ọjọ keji oṣu Keje, si ọjọ kẹtalelogun, oṣu Keje. Ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ akọkọ lati ṣide yoo waye laarin Morocco ati Burkina Faso ni papa isere Prince Moulay Abdellah n'ilu Rabat. Oríṣun àwòrán, caf Ẹgbẹ agbabọọlu Naijiria, Super Falcons, lo gba ife naa ni idije mẹta to kọja, wọn si ti gba a nígbà mẹsan-an, ninu igba mọkanla ti idije naa ti waye. Ipin C ni Naijiria wa ninu idije ti ọdun yii. Ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ wọn àkọ́kọ́ yoo waye lọjọ Aje pẹlu orile-ede South Africa. Lẹyin naa ni wọn o koju Botswana ati Burundi. Ohun kan to jẹ mímọ̀ ni pe lati ìbẹ̀rẹ̀ ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ wọn àkọ́kọ́, ni Super Falcons ti ma n gba jọba idije. Àwọn agbabọọlu Naijiria to n sisẹ nilẹ okeere, pọ laarin àwọn ọmọ ikọ Super Falcons. Lara wọn ni Asisat Oshoala, ọmọ ẹgbẹ́ agbabọọlu Spain. Oun naa ni balogun ikọ Super Falcons. Ni opin idije WAFCON 2022 yii, ẹgbẹ́ agbabọọlu orile-ede to ba bori yoo ni anfaani lati kopa ni idije ife agbaye lọdun to n bọ. Bakan naa, orile-ede mẹrin to ba de ipele to kangun si aṣekagba, semi-final, yoo ni anfaani lati lọ si Australia ati New Zealand. Ẹgbẹrun lọ́nà ẹẹdẹgbẹta Dọla ni ẹ̀bùn owo ti orile-ede to ba borí ni WAFCON 2022 yoo gba.",2 Agẹmo 2022 | ||
| Ìjọba Nàìjíríà yí ìpinnu rẹ̀ padà lórí àjọ eré ìdárayá bọ́ọ̀lù alápẹ̀rẹ̀ tó bẹ́gilé tẹ́lẹ̀," Oríṣun àwòrán, D'tigers/nigeria basketball Ijọba orile-ede Naijiria ti yi ìpinnu pada lori ere idaraya gbigbabọọlu sáwọn lẹyin ti wọn yoo ọwọ ninu ifieyẹ agbaye losu to lọ. | ||
|
|
||
| Ajọ to rí sì ere idaraya ati oun to jọ mọ awọn ọdọ lorile-ede Naijiria ni awọn o ni kopa ninu ifesewonse kankan latari iṣẹlẹ kan to waye ni apa guusu ilẹ adulawo. |
ruohoruotsi
reviewed
Oct 15, 2022
BBC/bbc-sport-yoruba.csv
Outdated
| @@ -0,0 +1,370 @@ | |||
| headline,contents,date | |||
Member
There was a problem hiding this comment.
Please remove this metadata from the text
ruohoruotsi
reviewed
Oct 15, 2022
BBC/bbc-sport-yoruba.csv
Outdated
| Africa to n lọ lọwọ ni Morocco. Eyi waye lẹyin ti wọn lu ẹgbẹ́ agbabọọlu Indomitable | ||
| Lionesses ti orile-ede Cameroon ni ami ayo kan si odo. Ọjọbọ ni ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ naa waye ni papa ìṣeré Mohammed V | ||
| n'ilu Casablanca. Ọmi odo ni ẹgbẹ́ agbabọọlu mejeeji ta ní abala àkọ́kọ́ ifẹsẹ̀wọnsẹ̀ | ||
| naa. Sugbọn nigba ti ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ wọ isẹju mẹrindinlọgọfa, |
Member
There was a problem hiding this comment.
The text generally is very raw and need some processing before we can call it a BBC YO NEWS corpus. For starters, it is not better if each new sentence is on a new line?
ruohoruotsi
reviewed
Oct 15, 2022
removed headline, content, date
This file contains hidden or bidirectional Unicode text that may be interpreted or compiled differently than what appears below. To review, open the file in an editor that reveals hidden Unicode characters.
Learn more about bidirectional Unicode characters
Sign up for free
to join this conversation on GitHub.
Already have an account?
Sign in to comment
Add this suggestion to a batch that can be applied as a single commit.This suggestion is invalid because no changes were made to the code.Suggestions cannot be applied while the pull request is closed.Suggestions cannot be applied while viewing a subset of changes.Only one suggestion per line can be applied in a batch.Add this suggestion to a batch that can be applied as a single commit.Applying suggestions on deleted lines is not supported.You must change the existing code in this line in order to create a valid suggestion.Outdated suggestions cannot be applied.This suggestion has been applied or marked resolved.Suggestions cannot be applied from pending reviews.Suggestions cannot be applied on multi-line comments.Suggestions cannot be applied while the pull request is queued to merge.Suggestion cannot be applied right now. Please check back later.
No description provided.